fbpx

[Download] Agbara Jesu – Iyabo Idowu Ft. Kay Wonder

Iyabo Idowu Olamiposi, an upcoming gospel musician, has released a highly anticipated single titled “Agbara Jesu,” which features prolific music minister, Kay Wonder.

Agbara Jesu is a song about Jesus’ power and strength that is sure to affect listeners’ hearts and souls. It also represents Iyabo’s vocal abilities and spiritual connection to her faith in a powerful and inspiring way.

Iyabo Idowu’s music has always been a source of inspiration and encouragement, from her debut single, Emi Mimo (Holy Spirit), to AbaniseGbigbe GaAlasepeOba NlaJenrogo Lo, and others, this latest release is no exception.

As a great composer and songwriter with a distinct voice and excellent lyrics, Agbara Jesu’ melodious sound will definitely uplift you. 

Stream & Download Below

Agbara Jesu – Iyabo Idowu

Lyrics: Agbara Jesu By Iyabo Idowu Ft. Kay Wonder

Ooh oh
Eyah ne ya ya ah

Agbara jesu wa sibe
Agbara jesu wa laaye
Agbara toun gbani
Lowo alagbara ton nini lara
Ese gbanigbani ti gbogbo aye n saya

Ese gbanigbani ti gbogbo aye n saya
Ese gbanigbani ti gbogbo aye n kepe eh eh
Agbara toun gbani
Lowo alagbara toun nini lara
Ese gbanigbani ti gbogbo aye n saya

Lebra nunane yadah
Lebra nunee

Agbaara ah

Agbara jesu wa sibe
Agbara jesu wa laaye
Agbara toun gbani
Lowo alagbara ton nini lara
Ese gbanigbani ti gbogbo aye n saya

Ese o gbanigbani

Ese gbanigbani ti gbogbo aye n saya
Ese gbanigbani ti gbogbo aye n kepe
Agbara toun gbani
Lowo alagbara toun nini lara
Ese gbanigbani ti gbogbo aye n saya

Jesu ni gbanigbani ti gbogbo aye n saya
Oran mo nise fayati atofarati bi oke
Ato gboju le olufokantan olugbala araye
Ese gbanigbani ti gbogbo aye n saya
Je e su ni gbanigbani toun gbani
Lojo ogun le eh
Oran mo nise fayati atofarati bi i oke
Agbara toun gbani lowo alagbara
Toun gbaso lara eni
Ese gbanigbani ti gbogbo aye n saya

Ese ese eh eh

Ese gbanigbani ti gbogbo aye n saya
Ese gbanigbani ti gbogbo aye n kepe
Agbara toun gbani
Lowo alagbara toun nini lara
Ese gbanigbani ti gbogbo aye n saya

Agbara tope lasaru jade ninu iboji
Oku ojo kerin to di alaye logan
Agbara to pin okun niya
O sise imole fawon omo isreali
Ati okunkun fawon omo ogun farao
Loganjo oru eh
Owo agbara to soro lara ogiri
Eyin ni owo airi ton sise riri
To si ilekun irin inu tubu fun peteru
Kaabokasa
Agbara to kolu sioni ati oku oba basani
Agbara toun fowo agbara gbagbara lowo Alagbara tin fagbara nini laara

Ese o gbanigbani mi

Ese gbanigbani ti gbogbo aye n saya
Ese gbanigbani ti gbogbo aye n kepe
Agbara toun gbani
Lowo alagbara toun nini lara
Ese gbanigbani ti gbogbo aye n saya

Oh oh oh oh oh oh
Oh oh oh oh oh oh

Agbara to ju agbara lo
Agbara to ju agbara lo

Ema nuna ne e eyah

Agbara to ju agbara lo
Agbara to ju agbara lo

Levren gede doza

Oruko to ju oruko lo
Oruko to ju oruko lo

Ayaya namana noza

Oruko to ju oruko lo
Oruko to ju oruko lo

Ipa to bori ipa o
Ipa to bori ipa o

Matasa ni yadah

Agbara olorun ga o
Agbara re ga ju aye lo

Okun ri o osa jodani rio opada sehin
Awon oke nla n fo bi agbo

Agbara re gaju aye lo

Keke fo bi odo aguntan
Tani iwo oke niwaju serubabeli

Agbara re ga ju aye lo

Wariri iwo ile niwaju
Agbara olorun mi

Agbara re ga ju aye lo

Owonu ketekete balamu
Ofohun bi eniyan jade

Agbara re ga ju aye lo
Agbara to ju agbara lo
Jeesu
Atuni lara bi yinyin ati iri
Gbedugbedu awosanmo ape fohun
Ape dahun ape sohun gbogbo oo
Enito da gbogbo awon orun
Ninu awon orun
Oruko tenikankan ole daduro
Oruko toju gbogbo oruko lo
Oruko ti gbogbo oba aye n wari fun
Oruko ti gbogbo awon agbara aye
Nwari fun
Agbagba merinlelogun orun
Won fi ade won wole
Niwaju oruko to ju gbogbo oruko lo
Oruko ton ja ide oruko ton tu ide
Oruko apefohun apedahun
Olorun ayeeraya
Agbara ninu agbara awosanmo
Agbara ninu awon Agbara osumare
Agbara ninu awon Agbara gbogbo aye o
Jesu loruko re jesu loruko re
Eniti okun ati osa ri tosa
Ina toju gbogbo Ina
Ina ti gbogbo aye n wari fun
Kabiesi ooooo
Agbara re ga ju aye lo
Thank you jesus

Read More